Èrò Fífi Dúkìá Àfojúrí

About The Book

<p>Ìwé yìí nṣàlàyé èrò kan tí ó jẹ́ àrà-ọ̀tọ̀ nípa ojú òpó àgbáyé fún fífi dúkìá àfojúrí wé ara wọn (aapu) pẹ̀lú ìṣirò àfojúsùn ọjà títà tí ó jọjú (Biliọnu Dọla) tí a gbé wọ inú sọfwea ti ilé iṣẹ́ dúkìá àfojúrí títí dórí àyẹ̀wò dúkìá àfojúrí (ọjà títà tí ó lè tó Tiriliọnu Dọla).</p><p>Èyí ntúmọ̀ sí pé dúkìá àfojúrí fún gbígbé àti ìdókòwò bóyá ti àdáni àbí àyálò ni a lè ṣe alárinà fún ní ọ̀nà tí ó múná dóko tí kò sì fi àkókò ṣòfò. Òun ni ọjọ́ ọ̀la ṣíṣe alárinà dúkìá àfojúrí tí ó jẹ́ ọ̀tun tí ó sì dára fún gbogbo àwọn aṣojú fún dúkìá àfojúrí àti àwọn tí ó ní dúkìá. Ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ pé gbogbo orílẹ̀-edè ni fífi dúkìá àfojúrí wé ara wọn ti ní ìtumọ̀ títí dé orílè-èdè kan sí èkejì.</p><p>Dípò “gbígbé” dúkìá wá sí ọ̀dọ̀ olùrà àbí ẹni tí ó fẹ́ yá a lò níwọ̀n ìgbà tí ojú òpó fífi dúkìá àfojúrí wé ara wọn ti wà àwọn tí ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ olùrà àti olùyálò lè kún ojú òṣùwọ̀n (wá àkọsílẹ̀) kí a sì fi wọ́n wé ara wọn kí a sì fi wọ́n mọ dúkìá tí àwọn aṣojú dúkìá àfojúrí bá gbé jáde.</p>
Piracy-free
Piracy-free
Assured Quality
Assured Quality
Secure Transactions
Secure Transactions
Delivery Options
Please enter pincode to check delivery time.
*COD & Shipping Charges may apply on certain items.
Review final details at checkout.
downArrow

Details


LOOKING TO PLACE A BULK ORDER?CLICK HERE