Ológbò Olùwòsàn Náà: Yorùbá Edition of The Healer Cat
Yoruba


LOOKING TO PLACE A BULK ORDER?CLICK HERE

Piracy-free
Piracy-free
Assured Quality
Assured Quality
Secure Transactions
Secure Transactions
Fast Delivery
Fast Delivery
Sustainably Printed
Sustainably Printed
Delivery Options
Please enter pincode to check delivery time.
*COD & Shipping Charges may apply on certain items.
Review final details at checkout.

About The Book

Celesse the healer cat is a highly respected member of the neighborhood. As the mistresss favorite cat she spends lazy days in the warmth of the house. One snowy night a mother hare rushes in desperate for help. Reluctantly the healer cat travels with her through a nighttime snowstorm and biting cold winds. In a dark forest Celesse comes face-to-face with a scary surprise and is forced to gather her powers for the first time in a while. --- Nítorí ẹ̀bùn rẹ̀ Celesse ológbò olùwòsàn jẹ́ ẹni tí a pọ́nlé gidi ní àdúgbò rẹ̀. Gẹ́gẹ́ bí ààyò fún ìyá àgbà ó fẹ́ràn láti máa gbádùn àkókò tí kò bá níṣẹ́ nínú ilé rẹ̀. Ṣùgbọ́n nígbà náà ìyá ehoro kan wọlé tí ó nbéèrè fún ìrànlọ́wọ́. Ìtẹnumọ́ rẹ̀ borí ìlọ́ra ti ológbò olùwòsàn tí ó nmú u là yìnyín líle kọjá. Nínú igbó dúdú kan Celesse dojúkọ ìyanu kan èyí tí ó mú kí ó súnrakì. Ní kété tí òru náà àti ìrìnàjò náà parí oòrùn jáde èyí tí ó fà ìlọ́wọ́wọ́ sórí àwọn ewéko àti sí ọkàn ológbò olùwòsàn.
downArrow

Details