<p>Awọn itan Bibeli ti inu iwe yi yio jẹ iranwọ fun awọn ọmọde lati mọ pe (ranti pe) ohunkohun yo wu ti ńsẹlẹ ninu aiye wọn tabi ni ayika wọn Ọlọrun ntọju bẹni O si ńsọ wọn lọsan ati loru. Ko dabi awọn obi wa Ọlọrun ki i sun tabi ko sarẹ. Ọlọrun si mọ ọjọ waju. O jẹ olododo ati Ẹniti ńpa adehun Rẹ mọ.</p>
Piracy-free
Assured Quality
Secure Transactions
Delivery Options
Please enter pincode to check delivery time.
*COD & Shipping Charges may apply on certain items.